Connect with us

Hi, what are you looking for?

Lyrics

Showa – Kizz Daniel

Ahn-ahn

Alákọri, alakọkọ, ṣ’ómá fẹ mí? Ṣ’ómá là tán?
Tí ń bà gbé wá (whoo), ṣ’ómá ká kọ?
Ṣé mo máa ní problem pẹlú boys?
Ta bà já, ká padà, má sá lọ Canada
If I travel today, kí ń má bà ẹ l’ababa (l’ababa)
Army man na my army man
Army man na my brother man
Ó lè ní problem

Ahh, baby, ṣ’ówa pá oh? (Ṣ’ówá pá?)
Ṣó need mi kì ń call in? (Àwọn eléyìí)
Mo láyé lo máa jẹ kù o
Ìrù eléyìí ó mà ní problem (kan)
Melanin poppin’, baby, nìṣó ní tá
Baby, sunshine give you filter
Onidiri ńbẹ, oh-yeah, oh-wururu rarurábà

Ṣ’òní capital business? (Ṣ’owá?)
Ṣ’òní character deaconess? (Ṣ’owá?)
Can you wake up around 4:30 (ṣ’owá?)
To make breakfast for me? (Ṣ’owá?)
Tó bà dálẹ, ṣ’olè gimme-gimme? (Ṣ’owá?)
Gimme-gimme, kò má gbọn mí jìgì (ṣ’owá?)
Gimme-gimme, k’oma gbọn mi jigi (ṣ’owá?)
Oh-ooh-oh

Long time ago, I say no kele fit make me conform, ooh-yah
Ò ká mí mọ corner (ṣ’ó)
Now, I won do am, now, I won run am (oya, uh)
Very gentle girl (whoo)
I’ll pick you up, turn you biggie girl (biggie girl)
Mama say, “I don fall in love”
And my papa say, “Ọmọ, jẹun lọ”

Ahh, baby, ṣ’ówa pá oh? (Ṣ’ówá pá?)
Ṣó need mi kì ń call in? (Àwọn eléyìí)
Mo láyé lo máa jẹ kù o
Ìrù eléyìí ó mà ní problem (kan)
Melanin popping, baby, nìṣó ní tá
Baby, sunshine give you filter
Onidiri ńbẹ, oh-yeah, oh-wururu, rarurábà

Ṣ’òní capital business? (Ṣ’owá?)
Ṣ’òní character deaconess? (Ṣ’owá?)
Can you wake up around 4:30 (ṣ’owá?)
To make breakfast for me? (Ṣ’owá?)
Tó bà dálẹ, ṣ’olè gimme-gimme? (Ṣ’owá?)
Gimme-gimme, kò má gbọn mí jìgì (ṣ’owá?)
Gimme-gimme, k’oma gbọn mi jigi (ṣ’owá?)
Oh-ooh-oh

Oh-ooh-oh
(Ṣ’owá?)
(Ṣ’owá?)
(Ṣ’owá?)
(Ṣ’owá?) Oh-ooh-oh

Songwriters: Oluwatobiloba Anidugbe / Azuka Akaeze

Click to comment

Leave a Reply

Your email address will not be published. Required fields are marked *

Latest

Celebrity News

Nigerian stars Odumodublvck and Burna Boy were among the big names at the 2024 BET Hip Hop Awards, but neither managed to secure a...

Music

Nigerian Afrobeats heavyweights BNXN and Rema have finally joined forces on their electrifying new single, “Fi Kan We Kan”, released via EMPIRE. This much-anticipated...

Celebrity News

Afrobeats sensation Oxlade has revealed that he feels more appreciated in Ghana than in his home country, Nigeria, while also addressing personal and professional...

Advertisement

You May Also Like

Celebrity News

Afrobeats star Kizz Daniel continues his celebration of a decade in the music industry with the release of two new singles, “Marhaba” and “We...

Music

Afrobeats star Kizz Daniel has officially surpassed 1 billion streams on Spotify across all credits, solidifying his position as one of Nigeria’s most successful...

Music

Afrobeats continues its global takeover, and this year’s Afro Nation festival in Detroit was a powerful display of its international appeal. Held on August...

Music

In a groundbreaking achievement, Kizz Daniel’s hit single ‘Twe Twe’ featuring Davido has emerged as the most streamed song in Nigeria for the first...